Nọ́ńbà 26:59 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 59 Orúkọ ìyàwó Ámúrámù sì ni Jókébédì,+ ọmọ Léfì, tí ìyàwó rẹ̀ bí fún un ní Íjíbítì. Ó wá bí Áárónì àti Mósè àti Míríámù+ arábìnrin wọn fún Ámúrámù.
59 Orúkọ ìyàwó Ámúrámù sì ni Jókébédì,+ ọmọ Léfì, tí ìyàwó rẹ̀ bí fún un ní Íjíbítì. Ó wá bí Áárónì àti Mósè àti Míríámù+ arábìnrin wọn fún Ámúrámù.