Ẹ́kísódù 4:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Jèhófà wá sọ fún Áárónì pé: “Lọ bá Mósè nínú aginjù.”+ Torí náà, ó lọ pàdé rẹ̀ ní òkè Ọlọ́run tòótọ́,+ ó sì fi ẹnu kò ó lẹ́nu láti kí i.
27 Jèhófà wá sọ fún Áárónì pé: “Lọ bá Mósè nínú aginjù.”+ Torí náà, ó lọ pàdé rẹ̀ ní òkè Ọlọ́run tòótọ́,+ ó sì fi ẹnu kò ó lẹ́nu láti kí i.