-
Léfítíkù 16:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “Kó wá jáde wá síbi pẹpẹ+ tó wà níwájú Jèhófà, kó ṣe ètùtù fún un, kó sì mú lára ẹ̀jẹ̀ akọ màlúù náà àti lára ẹ̀jẹ̀ ewúrẹ́ náà, kó wá fi sára àwọn ìwo tó wà ní gbogbo ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ. 19 Kó tún fi ìka rẹ̀ wọ́n lára ẹ̀jẹ̀ náà sára pẹpẹ lẹ́ẹ̀méje, kó lè wẹ̀ ẹ́ mọ́, kó sì sọ ọ́ di mímọ́ kúrò nínú ìwà àìmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
-