ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 38:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Lẹ́yìn náà, ó fi bàbà ṣe bàsíà+ àti ẹsẹ̀ bàsíà náà; ó lo dígí* àwọn obìnrin tí wọ́n ṣètò pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ ìsìn ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.

  • Léfítíkù 8:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Lẹ́yìn náà, ó wọ́n lára rẹ̀ sórí pẹpẹ lẹ́ẹ̀méje, ó sì fòróró yan pẹpẹ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ àti bàsíà àti ẹsẹ̀ rẹ̀ láti yà wọ́n sí mímọ́.

  • 1 Àwọn Ọba 7:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Ó ṣe bàsíà bàbà+ mẹ́wàá; ogójì (40) òṣùwọ̀n báàtì ni bàsíà kọ̀ọ̀kan ń gbà. Ìwọ̀n bàsíà kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin.* Kẹ̀kẹ́ ẹrù mẹ́wẹ̀ẹ̀wá náà ní bàsíà kọ̀ọ̀kan lórí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́