Nọ́ńbà 3:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 kí o gba ṣékélì* márùn-ún lọ́wọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan,+ kó jẹ́ ìwọ̀n ṣékélì ibi mímọ́.* Ṣékélì kan jẹ́ ogún (20) òṣùwọ̀n gérà.*+
47 kí o gba ṣékélì* márùn-ún lọ́wọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan,+ kó jẹ́ ìwọ̀n ṣékélì ibi mímọ́.* Ṣékélì kan jẹ́ ogún (20) òṣùwọ̀n gérà.*+