Nọ́ńbà 3:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Orúkọ àwọn ọmọkùnrin Áárónì nìyí: Nádábù àkọ́bí, Ábíhù,+ Élíásárì+ àti Ítámárì.+ 3 Èyí ní àwọn ọmọkùnrin Áárónì, àwọn àlùfáà tí wọ́n fòróró yàn, tí wọ́n fi iṣẹ́ àlùfáà+ lé lọ́wọ́.*
2 Orúkọ àwọn ọmọkùnrin Áárónì nìyí: Nádábù àkọ́bí, Ábíhù,+ Élíásárì+ àti Ítámárì.+ 3 Èyí ní àwọn ọmọkùnrin Áárónì, àwọn àlùfáà tí wọ́n fòróró yàn, tí wọ́n fi iṣẹ́ àlùfáà+ lé lọ́wọ́.*