Ẹ́kísódù 40:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Kí o fòróró yàn wọ́n bí o ṣe fòróró yan bàbá wọn,+ kí wọ́n lè di àlùfáà mi, ìran wọn á sì máa ṣiṣẹ́ àlùfáà títí lọ torí o ti fòróró yàn wọ́n.”+
15 Kí o fòróró yàn wọ́n bí o ṣe fòróró yan bàbá wọn,+ kí wọ́n lè di àlùfáà mi, ìran wọn á sì máa ṣiṣẹ́ àlùfáà títí lọ torí o ti fòróró yàn wọ́n.”+