Léfítíkù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “‘Kí ẹ fi iyọ̀ dun gbogbo ọrẹ ọkà tí ẹ bá mú wá; ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí iyọ̀ májẹ̀mú Ọlọ́run yín di àwátì nínú ọrẹ ọkà yín. Kí ẹ máa fi iyọ̀+ sí gbogbo ọrẹ yín.
13 “‘Kí ẹ fi iyọ̀ dun gbogbo ọrẹ ọkà tí ẹ bá mú wá; ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí iyọ̀ májẹ̀mú Ọlọ́run yín di àwátì nínú ọrẹ ọkà yín. Kí ẹ máa fi iyọ̀+ sí gbogbo ọrẹ yín.