-
Ẹ́kísódù 28:9-11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “Kí o mú òkúta ónísì méjì,+ kí o sì fín orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì sára wọn,+ 10 orúkọ mẹ́fà lára òkúta kan, orúkọ mẹ́fà tó ṣẹ́ kù lára òkúta kejì, bí wọ́n ṣe bí wọn tẹ̀ léra. 11 Kí oníṣẹ́ ọnà òkúta fín orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì sára òkúta méjèèjì bí ìgbà tó ń fín èdìdì.+ Kí o wá fi wúrà tẹ́lẹ̀ wọn.
-