Ẹ́kísódù 37:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ó wá fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe tábìlì.+ Gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+
10 Ó wá fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe tábìlì.+ Gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+