ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 8:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Sọ fún Áárónì pé, ‘Na ọ̀pá ọwọ́ rẹ sórí àwọn odò, àwọn ipa odò Náílì àti àwọn irà, kí o sì mú kí àkèré bo ilẹ̀ Íjíbítì.’”

  • Ẹ́kísódù 17:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Máa lọ níwájú àwọn èèyàn náà, kí o sì mú lára àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì dání pẹ̀lú ọ̀pá rẹ tí o fi lu odò Náílì.+ Mú un dání kí o sì máa lọ. 6 Wò ó! Èmi yóò dúró níwájú rẹ lórí àpáta tó wà ní Hórébù. Kí o lu àpáta náà, omi yóò jáde látinú rẹ̀, àwọn èèyàn náà á sì mu ún.”+ Mósè ṣe bẹ́ẹ̀ níṣojú àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì.

  • Nọ́ńbà 20:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ni Mósè bá gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè, ó sì fi ọ̀pá rẹ̀ lu àpáta náà lẹ́ẹ̀mejì, omi púpọ̀ wá ń tú jáde, àpéjọ náà àtàwọn ẹran ọ̀sìn wọn sì bẹ̀rẹ̀ sí í mu ún.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́