Ẹ́kísódù 35:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọjọ́ mẹ́fà ni kí ẹ fi ṣiṣẹ́, àmọ́ kí ọjọ́ keje jẹ́ mímọ́ fún yín. Kí ọjọ́ náà jẹ́ sábáàtì fún Jèhófà, ọjọ́ ìsinmi tí ẹ ò ní ṣiṣẹ́ rárá.+ Ṣe ni kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá ṣiṣẹ́ ní ọjọ́ náà.+ Nọ́ńbà 15:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wà ní aginjù, wọ́n rí ọkùnrin kan tó ń ṣa igi ní ọjọ́ Sábáàtì.+ Nọ́ńbà 15:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Ẹ gbọ́dọ̀ pa+ ọkùnrin náà, kí gbogbo àpéjọ sọ ọ́ ní òkúta ní ẹ̀yìn ibùdó.”+
2 Ọjọ́ mẹ́fà ni kí ẹ fi ṣiṣẹ́, àmọ́ kí ọjọ́ keje jẹ́ mímọ́ fún yín. Kí ọjọ́ náà jẹ́ sábáàtì fún Jèhófà, ọjọ́ ìsinmi tí ẹ ò ní ṣiṣẹ́ rárá.+ Ṣe ni kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá ṣiṣẹ́ ní ọjọ́ náà.+
35 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Ẹ gbọ́dọ̀ pa+ ọkùnrin náà, kí gbogbo àpéjọ sọ ọ́ ní òkúta ní ẹ̀yìn ibùdó.”+