Ẹ́kísódù 20:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “O ò gbọ́dọ̀ gbẹ́ ère kankan fún ara rẹ tàbí kí o ṣe ohun* kan tó dà bí ohunkóhun lókè ọ̀run tàbí ní ayé tàbí nínú omi nísàlẹ̀.+ Nehemáyà 9:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kódà nígbà tí wọ́n ṣe ère onírin* ọmọ màlúù fún ara wọn, tí wọ́n sì ń sọ pé, ‘Ọlọ́run rẹ nìyí tó mú ọ jáde kúrò ní Íjíbítì,’+ tí wọ́n hu ìwà àìlọ́wọ̀ tó bùáyà, Sáàmù 106:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Wọ́n ṣe ère ọmọ màlúù kan ní Hórébù,Wọ́n sì forí balẹ̀ fún ère onírin;*+20 Wọ́n gbé ògo miFún ère akọ màlúù tó ń jẹ koríko.+
4 “O ò gbọ́dọ̀ gbẹ́ ère kankan fún ara rẹ tàbí kí o ṣe ohun* kan tó dà bí ohunkóhun lókè ọ̀run tàbí ní ayé tàbí nínú omi nísàlẹ̀.+
18 Kódà nígbà tí wọ́n ṣe ère onírin* ọmọ màlúù fún ara wọn, tí wọ́n sì ń sọ pé, ‘Ọlọ́run rẹ nìyí tó mú ọ jáde kúrò ní Íjíbítì,’+ tí wọ́n hu ìwà àìlọ́wọ̀ tó bùáyà,
19 Wọ́n ṣe ère ọmọ màlúù kan ní Hórébù,Wọ́n sì forí balẹ̀ fún ère onírin;*+20 Wọ́n gbé ògo miFún ère akọ màlúù tó ń jẹ koríko.+