-
Ẹ́kísódù 18:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Kí o kìlọ̀ fún wọn nípa ohun tí àwọn ìlànà àtàwọn òfin sọ,+ kí o sì jẹ́ kí wọ́n mọ ọ̀nà tí wọ́n á máa rìn àti ohun tí wọ́n á máa ṣe.
-