Ẹ́kísódù 34:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó sọ pé: “Jèhófà, tí mo bá ti rí ojúure rẹ, jọ̀ọ́ Jèhófà, máa bá wa lọ kí o sì wà láàárín wa,+ bó tiẹ̀ jẹ́ pé alágídí* ni wá,+ kí o dárí àṣìṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ wa jì,+ kí o sì mú wa bí ohun ìní rẹ.” Diutarónómì 9:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí náà, mọ̀ pé kì í ṣe torí òdodo rẹ ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe máa fún ọ ní ilẹ̀ dáradára yìí kí o lè gbà á, torí alágídí* ni ọ́.+ Ìṣe 7:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 “Ẹ̀yin olóríkunkun àti aláìkọlà* ọkàn àti etí, gbogbo ìgbà lẹ̀ ń ta ko ẹ̀mí mímọ́; bí àwọn baba ńlá yín ti ṣe náà lẹ̀ ń ṣe.+
9 Ó sọ pé: “Jèhófà, tí mo bá ti rí ojúure rẹ, jọ̀ọ́ Jèhófà, máa bá wa lọ kí o sì wà láàárín wa,+ bó tiẹ̀ jẹ́ pé alágídí* ni wá,+ kí o dárí àṣìṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ wa jì,+ kí o sì mú wa bí ohun ìní rẹ.”
6 Torí náà, mọ̀ pé kì í ṣe torí òdodo rẹ ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe máa fún ọ ní ilẹ̀ dáradára yìí kí o lè gbà á, torí alágídí* ni ọ́.+
51 “Ẹ̀yin olóríkunkun àti aláìkọlà* ọkàn àti etí, gbogbo ìgbà lẹ̀ ń ta ko ẹ̀mí mímọ́; bí àwọn baba ńlá yín ti ṣe náà lẹ̀ ń ṣe.+