Sáàmù 106:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Nítorí wọn, á rántí májẹ̀mú rẹ̀,Àánú á sì ṣe é* nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tó ga tí kì í sì í yẹ̀.*+