Diutarónómì 9:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Mo bá yíjú pa dà, mo sì sọ̀ kalẹ̀ lórí òkè náà nígbà tí iná ń jó lórí rẹ̀,+ wàláà májẹ̀mú méjì náà sì wà ní ọwọ́ mi méjèèjì.+
15 “Mo bá yíjú pa dà, mo sì sọ̀ kalẹ̀ lórí òkè náà nígbà tí iná ń jó lórí rẹ̀,+ wàláà májẹ̀mú méjì náà sì wà ní ọwọ́ mi méjèèjì.+