-
Ìṣe 7:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Nítorí náà, wọ́n ṣe ère ọmọ màlúù kan lákòókò yẹn, wọ́n mú ẹbọ wá fún ère náà, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbádùn ara wọn nítorí àwọn iṣẹ́ ọwọ́ wọn.+
-