Diutarónómì 9:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Lẹ́yìn náà, mo mú ohun tí ẹ ṣe tó mú kí ẹ dẹ́ṣẹ̀, ìyẹn ọmọ màlúù náà,+ mo sì dáná sun ún; mo fọ́ ọ túútúú, mo sì lọ̀ ọ́ kúnná títí ó fi di lẹ́búlẹ́bú bí eruku, mo sì dà á sínú odò tó ń ṣàn látorí òkè náà.+
21 Lẹ́yìn náà, mo mú ohun tí ẹ ṣe tó mú kí ẹ dẹ́ṣẹ̀, ìyẹn ọmọ màlúù náà,+ mo sì dáná sun ún; mo fọ́ ọ túútúú, mo sì lọ̀ ọ́ kúnná títí ó fi di lẹ́búlẹ́bú bí eruku, mo sì dà á sínú odò tó ń ṣàn látorí òkè náà.+