Ẹ́kísódù 20:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe àwọn ọlọ́run fàdákà láti máa sìn wọ́n pẹ̀lú mi, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ ṣe àwọn ọlọ́run wúrà fún ara yín.+
23 Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe àwọn ọlọ́run fàdákà láti máa sìn wọ́n pẹ̀lú mi, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ ṣe àwọn ọlọ́run wúrà fún ara yín.+