Nọ́ńbà 16:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 “Ẹ̀yin méjèèjì, ẹ kúrò láàárín àpéjọ yìí, kí n lè pa wọ́n run lẹ́ẹ̀kan náà.”+ Ni wọ́n bá wólẹ̀.+