Ẹ́kísódù 13:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ní ọ̀sán, Jèhófà máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n ìkùukùu* kó lè máa darí wọn lójú ọ̀nà,+ àmọ́ ní òru, ó máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n iná* kó lè fún wọn ní ìmọ́lẹ̀, kí wọ́n lè máa bá ìrìn àjò wọn lọ tọ̀sántòru.+ Sáàmù 99:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó ń bá wọn sọ̀rọ̀ látinú ọwọ̀n ìkùukùu.*+ Wọ́n pa àwọn ìránnilétí rẹ̀ àti àṣẹ tó fún wọn mọ́.+
21 Ní ọ̀sán, Jèhófà máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n ìkùukùu* kó lè máa darí wọn lójú ọ̀nà,+ àmọ́ ní òru, ó máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n iná* kó lè fún wọn ní ìmọ́lẹ̀, kí wọ́n lè máa bá ìrìn àjò wọn lọ tọ̀sántòru.+