-
Nọ́ńbà 22:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Àmọ́ Ọlọ́run bínú sí i gidigidi torí pé ó ń lọ, áńgẹ́lì Jèhófà sì dúró ní ojú ọ̀nà láti dí i lọ́nà. Báláámù wà lórí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, méjì lára àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ ni wọ́n sì jọ ń lọ.
-