1 Kọ́ríńtì 10:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Bẹ́ẹ̀ kọ́; àmọ́ ohun tí mò ń sọ ni pé àwọn nǹkan tí àwọn orílẹ̀-èdè fi ń rúbọ, àwọn ẹ̀mí èṣù ni wọ́n fi ń rúbọ sí, kì í ṣe Ọlọ́run;+ mi ò sì fẹ́ kí ẹ di alájọpín pẹ̀lú àwọn ẹ̀mí èṣù.+
20 Bẹ́ẹ̀ kọ́; àmọ́ ohun tí mò ń sọ ni pé àwọn nǹkan tí àwọn orílẹ̀-èdè fi ń rúbọ, àwọn ẹ̀mí èṣù ni wọ́n fi ń rúbọ sí, kì í ṣe Ọlọ́run;+ mi ò sì fẹ́ kí ẹ di alájọpín pẹ̀lú àwọn ẹ̀mí èṣù.+