Ẹ́kísódù 34:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Ẹ fiyè sí ohun tí mò ń pa láṣẹ fún yín lónìí.+ Èmi yóò lé àwọn Ámórì kúrò níwájú yín àti àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Pérísì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì.+
11 “Ẹ fiyè sí ohun tí mò ń pa láṣẹ fún yín lónìí.+ Èmi yóò lé àwọn Ámórì kúrò níwájú yín àti àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Pérísì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì.+