-
Ẹ́kísódù 34:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Lẹ́yìn ìyẹn, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sún mọ́ ọn, ó sì sọ gbogbo àṣẹ tí Jèhófà pa fún un lórí Òkè Sínáì fún wọn.+