Ẹ́kísódù 30:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 “Kí o ṣe pẹpẹ kan láti máa fi sun tùràrí;+ igi bọn-ọ̀n-ní ni kí o fi ṣe é.+ Ẹ́kísódù 37:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ó wá fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe pẹpẹ tùràrí.+ Ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin dọ́gba, gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì. Pẹpẹ náà àti àwọn ìwo rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan.+ Ẹ́kísódù 40:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí o gbé pẹpẹ tùràrí+ tí wọ́n fi wúrà ṣe síwájú àpótí Ẹ̀rí, kí o sì ta aṣọ* sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìjọsìn.+
25 Ó wá fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe pẹpẹ tùràrí.+ Ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin dọ́gba, gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì. Pẹpẹ náà àti àwọn ìwo rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan.+
5 Kí o gbé pẹpẹ tùràrí+ tí wọ́n fi wúrà ṣe síwájú àpótí Ẹ̀rí, kí o sì ta aṣọ* sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìjọsìn.+