- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 22:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        7 “Tí ẹnì kan bá fi owó tàbí àwọn ohun kan pa mọ́ sọ́wọ́ ọmọnìkejì rẹ̀, tí olè wá jí àwọn nǹkan náà kó nílé onítọ̀hún, tí ẹ bá mú olè náà, kó fi nǹkan dípò ní ìlọ́po méjì.+ 
 
-