- 
	                        
            
            Léfítíkù 5:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        18 Kó mú àgbò tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá wá fún àlùfáà látinú agbo ẹran, láti fi rú ẹbọ ẹ̀bi,+ kí àgbò náà tó iye tí wọ́n dá lé e. Àlùfáà yóò wá ṣe ètùtù fún un torí àṣìṣe tó ṣe láìmọ̀ọ́mọ̀, yóò sì rí ìdáríjì. 
 
-