-
Léfítíkù 2:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 “‘Tó bá jẹ́ ohun tí wọ́n ṣe nínú agbada+ lo fẹ́ fi ṣe ọrẹ ọkà, kó jẹ́ èyí tí wọ́n fi ìyẹ̀fun tó kúnná ṣe, tí wọ́n pò mọ́ òróró, tí kò sì ní ìwúkàrà.
-