-
Ẹ́kísódù 29:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Àmọ́ kí o fi iná sun ẹran akọ màlúù náà pẹ̀lú awọ rẹ̀ àti ìgbẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn òde àgọ́. Ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ni.
-
-
Léfítíkù 1:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Kí wọ́n bó awọ ẹran náà, kí wọ́n sì gé e sí wẹ́wẹ́.+
-