ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 22:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 “Tí ẹ bá rú ẹbọ ìdúpẹ́ sí Jèhófà,+ kí ẹ rú ẹbọ náà kí ẹ bàa lè rí ìtẹ́wọ́gbà.

  • 2 Kíróníkà 29:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Lẹ́yìn náà, Hẹsikáyà sọ pé: “Ní báyìí tí a ti yà yín sọ́tọ̀* fún Jèhófà, ẹ mú àwọn ẹbọ àti àwọn ẹbọ ìdúpẹ́ wá sí ilé Jèhófà.” Ni ìjọ náà bá bẹ̀rẹ̀ sí í mú àwọn ẹbọ àti àwọn ẹbọ ìdúpẹ́ wá, gbogbo ẹni tí ọkàn rẹ̀ múra tán sì mú àwọn ẹbọ sísun wá.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́