Léfítíkù 22:29, 30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 “Tí ẹ bá rú ẹbọ ìdúpẹ́ sí Jèhófà,+ kí ẹ rú ẹbọ náà kí ẹ bàa lè rí ìtẹ́wọ́gbà. 30 Ọjọ́ yẹn ni kí ẹ jẹ ẹ́. Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣẹ́ ìkankan lára rẹ̀ kù di àárọ̀ ọjọ́ kejì.+ Èmi ni Jèhófà.
29 “Tí ẹ bá rú ẹbọ ìdúpẹ́ sí Jèhófà,+ kí ẹ rú ẹbọ náà kí ẹ bàa lè rí ìtẹ́wọ́gbà. 30 Ọjọ́ yẹn ni kí ẹ jẹ ẹ́. Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣẹ́ ìkankan lára rẹ̀ kù di àárọ̀ ọjọ́ kejì.+ Èmi ni Jèhófà.