-
Léfítíkù 11:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àmọ́ ohunkóhun tó wà nínú òkun àti odò tí kò ní lẹ́bẹ́ àti ìpẹ́, nínú gbogbo ẹ̀dá tó ń gbá yìn-ìn àti gbogbo ohun alààyè* míì tó wà nínú omi, ohun ìríra ló jẹ́ fún yín.
-
-
Diutarónómì 14:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àmọ́ ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tí kò bá ní lẹ́bẹ́ àti ìpẹ́. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín.
-