Léfítíkù 10:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kí ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ lọ́kùnrin àti lóbìnrin+ tún jẹ igẹ̀ ọrẹ fífì àti ẹsẹ̀ ìpín mímọ́+ ní ibi tó mọ́, torí mo ti fi ṣe ìpín rẹ àti ti àwọn ọmọ rẹ látinú ẹbọ ìrẹ́pọ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
14 Kí ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ lọ́kùnrin àti lóbìnrin+ tún jẹ igẹ̀ ọrẹ fífì àti ẹsẹ̀ ìpín mímọ́+ ní ibi tó mọ́, torí mo ti fi ṣe ìpín rẹ àti ti àwọn ọmọ rẹ látinú ẹbọ ìrẹ́pọ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.