Léfítíkù 7:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “‘Gbogbo ọrẹ ọkà tí wọ́n bá yan nínú ààrò tàbí tí wọ́n sè nínú páànù tàbí nínú agbada+ jẹ́ ti àlùfáà tó mú un wá. Yóò di tirẹ̀.+ 10 Àmọ́ gbogbo ọrẹ ọkà tí wọ́n pò mọ́ òróró+ tàbí tó gbẹ+ yóò jẹ́ ti gbogbo àwọn ọmọ Áárónì; ìpín kálukú máa dọ́gba.
9 “‘Gbogbo ọrẹ ọkà tí wọ́n bá yan nínú ààrò tàbí tí wọ́n sè nínú páànù tàbí nínú agbada+ jẹ́ ti àlùfáà tó mú un wá. Yóò di tirẹ̀.+ 10 Àmọ́ gbogbo ọrẹ ọkà tí wọ́n pò mọ́ òróró+ tàbí tó gbẹ+ yóò jẹ́ ti gbogbo àwọn ọmọ Áárónì; ìpín kálukú máa dọ́gba.