-
Ẹ́kísódù 29:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 “Ohun tí o máa ṣe láti yà wọ́n sí mímọ́ kí wọ́n lè di àlùfáà mi nìyí: Mú ọmọ akọ màlúù kan, àgbò méjì tí kò ní àbùkù,+