- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 39:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        27 Wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe aṣọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, ẹni tó ń hun aṣọ ló ṣe é,+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 39:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        29 wọ́n tún fi aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa, pẹ̀lú fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù àti òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò tí wọ́n hun pọ̀ ṣe ọ̀já, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè. 
 
-