ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 28:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ní ti àmùrè* tí wọ́n hun,+ èyí tó wà lára éfódì náà láti dì í mú kó lè dúró dáadáa, ohun kan náà ni kí wọ́n fi ṣe é, kí wọ́n lo wúrà, fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa.

  • Ẹ́kísódù 29:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Kí o wá kó àwọn aṣọ náà,+ kí o sì wọ aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ fún Áárónì, pẹ̀lú aṣọ àwọ̀lékè tí kò lápá tó máa wà lábẹ́ éfódì, kí o wọ éfódì náà fún un àti aṣọ ìgbàyà, kí o sì so àmùrè éfódì tí wọ́n hun* náà mọ́ ìbàdí rẹ̀ pinpin.+

  • Ẹ́kísódù 39:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Wọ́n tún ṣe òrùka wúrà méjì, wọ́n sì fi wọ́n síwájú éfódì náà, nísàlẹ̀ àwọn aṣọ èjìká méjèèjì éfódì náà, nítòsí ibi tí wọ́n ti so pọ̀, ní òkè ibi tí àmùrè* tí wọ́n hun ti so mọ́ éfódì náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́