Ẹ́kísódù 28:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Kí o fi Úrímù àti Túmímù*+ sínú aṣọ ìgbàyà ìdájọ́ náà, kí wọ́n sì máa wà ní àyà Áárónì nígbà tó bá wá síwájú Jèhófà, kí Áárónì máa gbé ohun tí wọ́n fi ń ṣe ìdájọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí àyà rẹ̀ níwájú Jèhófà nígbà gbogbo.
30 Kí o fi Úrímù àti Túmímù*+ sínú aṣọ ìgbàyà ìdájọ́ náà, kí wọ́n sì máa wà ní àyà Áárónì nígbà tó bá wá síwájú Jèhófà, kí Áárónì máa gbé ohun tí wọ́n fi ń ṣe ìdájọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí àyà rẹ̀ níwájú Jèhófà nígbà gbogbo.