Ẹ́kísódù 29:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Kí o wá mú lára ẹ̀jẹ̀ tó wà lórí pẹpẹ àti lára òróró àfiyanni náà,+ kí o sì wọ́n ọn sára Áárónì àti aṣọ rẹ̀ àti sára àwọn ọmọ rẹ̀ àti aṣọ wọn, kí òun àti aṣọ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ àti aṣọ wọn lè jẹ́ mímọ́.+
21 Kí o wá mú lára ẹ̀jẹ̀ tó wà lórí pẹpẹ àti lára òróró àfiyanni náà,+ kí o sì wọ́n ọn sára Áárónì àti aṣọ rẹ̀ àti sára àwọn ọmọ rẹ̀ àti aṣọ wọn, kí òun àti aṣọ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ àti aṣọ wọn lè jẹ́ mímọ́.+