- 
	                        
            
            Léfítíkù 6:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        28 Kí wọ́n fọ́ ìkòkò amọ̀ tí wọ́n fi sè é túútúú. Àmọ́ tó bá jẹ́ ìkòkò bàbà ni wọ́n fi sè é, kí wọ́n ha á, kí wọ́n sì fi omi fọ̀ ọ́. 
 
-