-
Ẹ́kísódù 29:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Kí àlùfáà tó bá rọ́pò rẹ̀ lára àwọn ọmọ rẹ̀ tó sì wá sínú àgọ́ ìpàdé láti ṣiṣẹ́ ní ibi mímọ́ wọ àwọn aṣọ náà fún ọjọ́ méje.+
-