Ẹ́kísódù 6:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Áárónì wá fi Élíṣébà, ọmọ Ámínádábù, arábìnrin Náṣónì+ ṣe aya. Ó bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítámárì+ fún un. 1 Kíróníkà 24:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nádábù àti Ábíhù kú ṣáájú bàbá wọn,+ wọn ò sì ní ọmọkùnrin kankan; àmọ́ Élíásárì+ àti Ítámárì ń ṣiṣẹ́ àlùfáà nìṣó.
23 Áárónì wá fi Élíṣébà, ọmọ Ámínádábù, arábìnrin Náṣónì+ ṣe aya. Ó bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítámárì+ fún un.
2 Nádábù àti Ábíhù kú ṣáájú bàbá wọn,+ wọn ò sì ní ọmọkùnrin kankan; àmọ́ Élíásárì+ àti Ítámárì ń ṣiṣẹ́ àlùfáà nìṣó.