Ẹ́kísódù 19:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Jẹ́ kí àwọn àlùfáà tó ń wá síwájú Jèhófà déédéé sọ ara wọn di mímọ́, kí Jèhófà má bàa pa* wọ́n.”+