-
Léfítíkù 9:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Áárónì sún mọ́ pẹpẹ, ó sì pa ọmọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ tó jẹ́ tirẹ̀.+
-
-
Léfítíkù 9:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Lẹ́yìn náà, ó pa ẹran ẹbọ sísun náà, àwọn ọmọ Áárónì gbé ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ fún un, ó sì wọ́n ọn sí gbogbo ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ náà.+
-