-
Diutarónómì 14:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “Nínú gbogbo ohun tó ń gbé inú omi, èyí tí ẹ lè jẹ nìyí: Ẹ lè jẹ ohunkóhun tó bá ní lẹ́bẹ́ àti ìpẹ́.+ 10 Àmọ́ ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tí kò bá ní lẹ́bẹ́ àti ìpẹ́. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín.
-