15 Tí ẹnikẹ́ni bá jẹ òkú ẹran tàbí èyí tí ẹran inú igbó fà ya,+ ì báà jẹ́ ọmọ ìbílẹ̀ tàbí àjèjì ló jẹ ẹ́, kó fọ aṣọ rẹ̀, kó fi omi wẹ̀, kó sì di aláìmọ́ títí di alẹ́;+ lẹ́yìn náà, á di mímọ́. 16 Àmọ́ tí kò bá fọ̀ wọ́n, tí kò sì wẹ̀, yóò jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.’”+