Diutarónómì 14:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Gbogbo ẹ̀dá abìyẹ́ tó ń gbá yìn-ìn* pẹ̀lú jẹ́ aláìmọ́ fún yín. Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ wọ́n.