-
Léfítíkù 15:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Tí ẹni tí nǹkan ń dà jáde lára rẹ̀ bá fara kan ohun èlò tí wọ́n fi amọ̀ ṣe, kí ẹ fọ́ ohun èlò náà túútúú, kí ẹ sì fi omi fọ ohun èlò èyíkéyìí tí wọ́n fi igi ṣe.+
-